GBÍGBÓGUNTI ÌFITÓNILÉTI ASINILỌ́NÀ NÍPA COVID-19 NÍ NÀÌJÍRÍÀ: AKÓJỌPỌ̀ ÀSÀYÀN ÌSẸ̀LẸ̀, ÀKÀNSE-ÌṢẸ́ LÁTI ỌWỌ́ ARN
Iwe yii kìí ṣe àkójọpọ̀ ìtàn àwọn oníróyìn àti àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ tí wọ́n wọ́gilé àìṣòótọ́ nìkan, ó tún jẹ́ ìtàn nípa ìrírí àwọn ènìyàn yìí gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára ọmọ ogun tí wọ́n gbé dìde láti jagun - kojú ìbẹ̀ru àìṣòótọ́, tó lè ṣekúpani gẹ́gẹ́ bi kòkòrò àìfojúrí bíi Kórónà.
₦0.00
Reviews
There are no reviews yet.