Description
TITLE: GBÍGBÓGUNTI ÌFITÓNILÉTI ASINILỌ́NÀ NÍPA COVID-19 NÍ NÀÌJÍRÍÀ
AUTHOR: AFRICA RESILIENCE NETWORK
ISBN: 978-978-991-598-9
GENRE: JOURNALISM / NON-FICTION
NO. OF PAGES: 124
YEAR: 2021
“Iwe yii kìí ṣe àkójọpọ̀ ìtàn àwọn oníróyìn àti àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ tí wọ́n wọ́gilé àìṣòótọ́ nìkan, ó tún jẹ́ ìtàn nípa ìrírí àwọn ènìyàn yìí gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára ọmọ ogun tí wọ́n gbé dìde láti jagun – kojú ìbẹ̀ru àìṣòótọ́, tó lè ṣekúpani gẹ́gẹ́ bi kòkòrò àìfojúrí bíi Kórónà. Mo nígbàgbọ́ pé ìwé yẹn yóò wúlò fún ìfikọ́ra iṣẹ́ akọ̀ròyìn, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ iṣẹ́ akọ̀ròyìn, àwọn oníṣẹ́ ìwádìí, àwọn àgbàọ̀jẹ̀ nípa ììfìdí-òótọ́ múlẹ̀, àwọn ilé-iṣẹ́ tí wọn ò gbára lé ìjọba, àti ẹnikẹ́ni tó bá nífẹ̀ sí gbígbógun ti àìṣòótọ́.” — Dayo Aiyetan, Executive Director ICIR
COMBATING COVID-19 MISINFORMATION IN NIGERIA: A COMPENDIUM OF SELECTED STORIES FROM THE ARN PROJECT was produced as part of IWPR’s AFRICA RESILIENCE NETWORK (ARN) programme, administered in partnership with the Centre for Information Resilience (CIR), The International Centre for Investigative Reporting (ICIR), and Africa Uncensored.
The compendium is also available in English, Hausa, Yoruba and Igbo languages.
Reviews
There are no reviews yet.